Get this song by Sunny Adé titled Omode O Mela. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.
Use the link below to stream and download Omode O Mela by Sunny Adé.
Lyrics Of Omode O Mela by Sunny Adé
Wọni ọmọde o Mela Olohun Mela katakata Wọni ọmọde o Mela Olohun Mela katakata Lai Mope èlà katakata ọba ija ni
Ore, kaso aja mole, kaso ẹkun mole Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọlá Koye won rara bwag eyi ga Lọlá Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Sunny Ade ode bi otin dé
Kaso aja mole, kaso ẹkun mole Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọla Koyewon rara Eyi bu wa eyi ga lola Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi Sunny Ade ode bi otin dé
Ọpọlọ ye eyin o fi eyin pamo kilon fi pamo fún Alangba yẹ eyin o fi pamo, kilon fi pamo fún Igun yẹ eyin, o fi eyin pamo, kilon fi pamo fún Igun ti o wa yẹ eyin to tun wa feyin pamo
Ati igun ati eyin rẹ, won o ṣe sebe je
Bi wọn ki wa gun lo Bi wọn ki wa gun tete Bi wọn ki wa gun lo Bi wọn ki wa gun tete Iho iho ni akara wa ti moi moi ti n ṣe oge
Ewé omo ogbon ṣe jube lo, omo logbe Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ewé kín gbo Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Igba ti o ṣe tiwon, o sọ sí rárá Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Àwa ṣe tiwa won pon ju koko Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ojú tó pọ koko kole tun lo sa morore Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Kingbo Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo Ojumo
DOWNLOAD SONG Wait For Me by Sunny Adé Ft Onyeka Onwenu Mp3 Download Get this song by Sunny Adé Ft Onyeka Onwenu titled Wait For Me. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a […]