Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé Mp3 Download
Get this song by Sunny Adé titled Ekilo Fomo Ode. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.
Use the link below to stream and download Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé.
Lyrics Of Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé
Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ
Bi obinrin fi oju doro, oro a gbe
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Kaluku l’omi se ti é
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Ki ẹyin ṣe t’ẹyin
Ki àwa ṣe t’awa
Kaluku l’omi se ti e
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru