Sunny Adé – Ara Ma Nfe Sinmi

                       DOWNLOAD SONG 

Ara Ma Nfe Sinmi by Sunny Adé Mp3 Download

Get this song by Sunny Adé titled Ara Ma Nfe Sinmi. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.

Use the link below to stream and download Ara Ma Nfe Sinmi by Sunny Adé.

Lyrics Of Ara Ma Nfe Sinmi by Sunny Adé

Ọrẹ rẹ die bínú bínú woni mo ku
Iya gbó ni lè ebi ń wá ní kiri
Iya gbó ni lè ọrẹ ń wá ní kiri
Tebi Tara tore, won temi lago
Lai mo wípé
Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo
Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo
Ototo larin wá, Ototo larin wá
Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa
Ọrẹ wá, ọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna
ọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna
Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ’run loju
Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ’run loju
Ìdájọ’ ó jìnnà, idajo ó jìnnà
Aye ẹ má dalekun
Torí mi ò báwọn wá, èmi ò ní báwọn lo
Mi ò báwọn wá, èmi ó ní báwọn lo
Torí, òtoto larin wa, òtoto larin wá
Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa
Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo
Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo
Ayé toto
Ọjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ọjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ọjọ’ ó rò se, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ara máa ń fẹ’, (ara máa ń fẹ’ simi)
E rọra ṣe (ara máa ń fẹ’ simi)
E rọra (ara máa ń fẹ’ simi)
Ara máa ń fẹẹ (ara máa ń fẹ’ simi)
Àní ara máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi)
Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)
Ọrẹ wá jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)
Ifakafiki làálàá lè (ara máa ń fẹ’ simi)
Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi)
Ará máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi)
Ifakafiki lórí ẹni (ara máa ń fẹ’ simi)
Ará máa ń fẹ’ (ara máa ń fẹ’ simi)
(End.)

Download Mp3 Here

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Next Post

Sunny Adé - Congratulation (Happy Birthday)

Fri Dec 6 , 2024
                       DOWNLOAD SONG  Congratulation (Happy Birthday) by Sunny Adé Mp3 Download Get this song by Sunny Adé titled Congratulation (Happy Birthday). Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He […]

You May Like

2Face Dibia 9ice Adekunle Gold Akon Asa Asake Ayra Starr Bella Shmurda Blaqbonez Burna Boy CKay Davido DJ Mix Duncan Mighty Erigga Falz Fireboy DML Flavour Frank Edward Harmonize Kizz Daniel Naira Marley Odumodublvck Olamide Omah Lay Oriental Brothers Osita Osadebe P-Square Patoranking Phyno Portable Rema Ruger Seyi Vibez Shatta Wale Simi Tekno Throwback Songs Timaya Tiwa Savage Umu Obiligbo Waje Wizkid Yemi Alade Zlatan