King Sunny Adé – Omode Omela

                       DOWNLOAD SONG 

Omode Omela by King Sunny Adé Mp3 Download

Get this song by King Sunny Adé titled Omode Omela. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.

Use the link below to stream and download Omode Omela by King Sunny Adé.

Lyrics Of Omode Omela by King Sunny Adé

Wọni ọmọde o MelaOlohun Mela katakataWọni ọmọde o MelaOlohun Mela katakataLai Mope èlà katakata ọba ija ni
Ore, kaso aja mole, kaso ẹkun moleTi aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowoKilefiri ni sí oyi bwag eyi ga LọláKoye won rarabwag eyi ga LọláKoyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdiỌlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdiSunny Ade ode bi otin dé
Kaso aja mole, kaso ẹkun moleTi aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowoKilefiri ni sí oyi bwag eyi ga LọlaKoyewon raraEyi bu wa eyi ga lolaKoyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdiỌlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdiSunny Ade ode bi otin dé
Ọpọlọ ye eyin o fi eyin pamo kilon fi pamo fúnAlangba yẹ eyin o fi pamo, kilon fi pamo fúnIgun yẹ eyin, o fi eyin pamo, kilon fi pamo fúnIgun ti o wa yẹ eyin to tun wa feyin pamo
Ati igun ati eyin rẹ, won o ṣe sebe je
Bi wọn ki wa gun loBi wọn ki wa gun teteBi wọn ki wa gun loBi wọn ki wa gun teteIho iho ni akara wa ti moi moi ti n ṣe oge
Ewé omo ogbon ṣe jube lo, omo logbeAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moEwé kín gboAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moIgba ti o ṣe tiwon, o sọ sí ráráAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moÀwa ṣe tiwa won pon ju kokoAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moOjú tó pọ koko kole tun lo sa mororeAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moKingboAfefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá moOjumo
 

Download Mp3 Here

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

You May Like

2Face Dibia 9ice Adekunle Gold Akon Asa Asake Ayra Starr Bella Shmurda Blaqbonez Burna Boy CKay Davido DJ Mix Duncan Mighty Erigga Falz Fireboy DML Flavour Frank Edward Harmonize Kizz Daniel Naira Marley Odumodublvck Olamide Omah Lay Oriental Brothers Osita Osadebe P-Square Patoranking Phyno Portable Rema Ruger Seyi Vibez Shatta Wale Simi Tekno Throwback Songs Timaya Tiwa Savage Umu Obiligbo Waje Wizkid Yemi Alade Zlatan