Get this song by King Sunny Adé titled Ekilo Fomo Ode. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.
Use the link below to stream and download Ekilo Fomo Ode by King Sunny Adé.
Lyrics Of Ekilo Fomo Ode by King Sunny Adé
Awo re gungun lobirin le ṣe Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ Bi obinrin fi oju doro, oro a gbe
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado Koma sesi fara ko odidan lojiji Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti é Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e
Ki àwon ṣe tiwọn Ki ẹyin ṣe t’ẹyin Ki àwa ṣe t’awa
Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e
Amò ṣá Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado Koma sesi fara ko odidan lojiji Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru