Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this song by King Sunny Adé titled Ara Ma Nfe Sinmi. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.
Use the link below to stream and download Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé.
Lyrics Of Ara Ma Nfe Sinmi by King Sunny Adé
Ọrẹ rẹ die bínú bínú woni mo ku
Iya gbó ni lè ebi ń wá ní kiri Iya gbó ni lè ọrẹ ń wá ní kiri Tebi Tara tore, won temi lago Lai mo wípé Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo Ototo larin wá, Ototo larin wá Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa Ọrẹ wá, ọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna ọjọ’ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ’run loju Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ’run loju Ìdájọ’ ó jìnnà, idajo ó jìnnà Aye ẹ má dalekun Torí mi ò báwọn wá, èmi ò ní báwọn lo Mi ò báwọn wá, èmi ó ní báwọn lo Torí, òtoto larin wa, òtoto larin wá Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo Ayé toto Ọjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo Ọjọ’ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo Ọjọ’ ó rò se, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo Ara máa ń fẹ’, (ara máa ń fẹ’ simi) E rọra ṣe (ara máa ń fẹ’ simi) E rọra (ara máa ń fẹ’ simi) Ara máa ń fẹẹ (ara máa ń fẹ’ simi) Àní ara máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi) Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi) Ọrẹ wá jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi) Ifakafiki làálàá lè (ara máa ń fẹ’ simi) Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ’ simi) Ará máa ń fẹ’ ó jare (ara máa ń fẹ’ simi) Ifakafiki lórí ẹni (ara máa ń fẹ’ simi) Ará máa ń fẹ’ (ara máa ń fẹ’ simi) (End.)