Aiye Nreti Eleya Mi by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this song by King Sunny Adé titled Aiye Nreti Eleya Mi. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.
Use the link below to stream and download Aiye Nreti Eleya Mi by King Sunny Adé.
Lyrics Of Aiye Nreti Eleya Mi by King Sunny Adé
Aiye n’reti eleya ‘mi o ‘Won n’reti eleya ‘mi o L’ojo ‘jumo ‘Won lo ko’rawon jo o Lati pe’gan ‘mi ‘Won ni, ‘mi o’mo ju’le adura L’ojo ‘jumo ‘Won ri ‘mi l’ona ile adura W’a ma’n pe’gan ‘mi W’a ‘lo tu tin’ulo Instrumental Interlude Aiye n’reti eleya ‘mi o ‘Won n’reti eleya ‘mi o L’ojo ‘jumo ‘Won ti ko’rawon jo o Lati pe’gan ‘mi ‘Won ni, ‘mi o’mo ju’le adura L’ojo ‘jumo B’on ri ‘mi l’ona ile adura W’a ma’n pe’gan ‘mi W’a ‘lo tu’ tin’lo W’a ‘ni “”oloju ‘rogodo bi ina oko”” “”Olori Gbeske”” “”E wa wo oni’ranu, ‘A je iya gbogbo O ma tu’ tin’lo”” W’a tun ma ‘wipe “”Baba adura, ro’ra mi a gbese”” Emi l’o ‘n ba’wi yen o, Olorun ‘mi, ‘So ‘ma wa wo ‘mi ni’ran ‘Ma je k’ogun aiye bo ‘mi mo’le Je k’enu ‘mi gb’oro l’oju ota ‘mi Je n’le so fun ‘won Pe ‘wo ‘nikan, l’oba n’la L’oju elegan o, Baba ponmile L””oju ‘won dakun da’mi l’ola L’opo L’opo Eyi ni mo ‘fe o Olorun mi Dakun ‘wa gb’emi ni’ja o ‘Itoripe… ‘Itotipe… Iwo ni ‘ki d’oju ti’ni ‘Itoripe… ‘Itoripe… Iwo ni ‘ki d’oju ti’ni Eledumare Baba ro’gbo o ‘Itoripe… (‘Itoripe…) ‘Itoripe… Iwo ni ‘ki d’oju ti’ni Instrumental Interlude