Sunny Adé – Ekilo Fomo Ode

                       DOWNLOAD SONG 

Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé Mp3 Download

Get this song by Sunny Adé titled Ekilo Fomo Ode. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success. The song will make your playlist if love good music.

Use the link below to stream and download Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé.

Lyrics Of Ekilo Fomo Ode by Sunny Adé

Awo re gungun lobirin le ṣe
Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ
Bi obinrin fi oju doro, oro a gbe
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti é
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Ki àwon ṣe tiwọn
Ki ẹyin ṣe t’ẹyin
Ki àwa ṣe t’awa
Konko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti e
Amò ṣá
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
 

Download Mp3 Here

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Next Post

Sunny Adé - Eri Okan (Conscience)

Fri Dec 6 , 2024
                       DOWNLOAD SONG  Eri Okan (Conscience) by Sunny Adé Mp3 Download Get this song by Sunny Adé titled Eri Okan (Conscience). Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He […]

You May Like

2Face Dibia 9ice Adekunle Gold Akon Asa Asake Ayra Starr Bella Shmurda Blaqbonez Burna Boy CKay Davido DJ Mix Duncan Mighty Erigga Falz Fireboy DML Flavour Frank Edward Harmonize Kizz Daniel Naira Marley Odumodublvck Olamide Omah Lay Oriental Brothers Osita Osadebe P-Square Patoranking Phyno Portable Rema Ruger Seyi Vibez Shatta Wale Simi Stanley Okorie Throwback Songs Timaya Tiwa Savage Umu Obiligbo Waje Wizkid Yemi Alade Zlatan

<